Oba Ni Jesu (Moti Sonu Sinu Igbekun Ese Mi) Lyrics by EmmaOMG
Listen below:
Oba Ni Jesu (Moti Sonu Sinu Igbekun Ese Mi) Lyrics
Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Oh! Oh! Oba ni Jesu
Mo ti sonu sinu igbekun ese mi
Si afonifoji iku a ti gbagbe mi
A ti to mi pin pe ko si ireti fun mi mo
Tori mo jebi gbogbo esun ta kan mo mi
Ide mi ja, mo d’ominira
Lati igba mo ti mo Jesu
A ti san gbese mi nipa Eje Jesu
Jesus, yours is the victory
Hallelujah! Praise the one who sets me free
Hallelujah! Death has lost his grip on me
You have broken every chain
There is salvation in your name
Jesus Christ, my living hope
Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Oh! Oh! Oba ni Jesu
Mo ti sonu sinu igbekun ese mi
Si afonifoji iku a ti gbagbe mi
A ti to mi pin pe ko si ireti fun mi mo
Tori mo jebi gbogbo esun ta kan mo mi
Ide mi ja, mo d’ominira
Lati igba mo ti mo Jesu
A ti san gbese mi nipa Eje Jesu
Jesus, yours is the victory
Hallelujah! Praise the one who sets me free
Hallelujah! Death has lost his grip on me
You have broken every chain
There is salvation in your name
Jesus Christ, my living hope